View Lyrics: Keresimesi (Christmas) Modal close icon

Viewing lyrics for Keresimesi (Christmas) by DAVID OKE (AGS).

Keresimesi (Christmas)
Written and arranged by David Oke
©AGSMUSIC2010

(Verse1)
Enukenu to ba n dupe ki ma ma Igbe rara (Any grateful mouth must not be dry)
Apere ti o ba n bo ara ile re ko ma gbodo jo (The basket that feeds his home must not lack)
Iyanu nla ni ife ti jesu ni si wa (this is a wonderful love that Jesus have for us)
Omo tuntun jojolo, ose (New born baby, thank you
To wa ra wa pada ni keresimesi yi (Who has come to redeem us all this Christmas)

(Chorus)
Keresimesi de (Christmas is here)
Keresimesi de (Christmas is here)
Odun ti a bi olugbala araye (The celebration of the day the savior is born)
Keresismesi de odun alayo (Christmas is here a celebration of Joy)
Ko san gbogbo wa sire loruko Jesu (May it bring joy to us all in Jesus name)

(Verse 2)
Awon orun n soro nigba ibi jesu olugbala o (the heavens declare the birth of Jesus the savior)
Je ki aye ki o ho iho ayo si oluwa (let the whole earth make a joyful noise unto the Lord)
Nitori a bi olugbala fun wa loni o (Because the savior is born today)
E je k’ayo (Let’s all rejoice)

(Vamp)
E yo (Rejoice)
Keresimesi de (Christmas is here)

Close